OGUN AJEOGUN
Ewe Ela, Atelewo inaki, oko ataare kan, ewe aAjeobale, epo obo ao jopo ao fi sin gbere yii orun owo mejeji ka . please do this first before doing all my medicine to make it work for u
IMULE AWON AGBALAGBA KIWON MALE DIWA LOWO-------
igbin apinu kan,oga
gbigbe kan,eku asin kan,ewe egele,yerepe,ewe kileofimise,ewe
ajeobale,opolo gbigbe kan,odidi atare kan,aojo papo aolo kuna,aote ni
osa meji,aope OHUN RE--igbin kiise eran taye nje,oga kiise eran apata,bi
abamu opolo lodo ti koba jo konko,amansole ni,eyin eleye e gbe mi ju
sile,e je kinri aiye temi se,agbe sole ni tewe egele,akopada niti
yerepe,aje kan ki gboju koje eku asin,aje kan ki gboju koje oga,aje kan
ki gboju kobale igi ajeobale,ki emale ba lemi mo,modi igi ajeobale
emi--omo-- tidi ewe kileofimise loni-adua.aomafi epo pupa la lalale.
OGUN ISOYE
Ao waa KuluSo meje, koriko ti esin jeku meje, igori aseseyo mariwo ope,
ikodie kan, ebose akuko adie ati irun abiya adie naa, ao wa lo be ogede
abo, ao fi ataare aja kan le lori, ao re ogede yen pelu ataare yen ao
mun wale, ao jo po, ao maa fi epo pupa laa ni araro fun ojo meje ki ato
so oro si enia kankan
ISORA /AGBELEPOTA TODAJU GAN..
....ORI AWONRIWON KAN,PATAKO ESIN,ISU
OGIRISAKO,ODIDI ATARE KAN,AOJO PAPO AOLO AORO SINU ADO ATO KAN,AOMA BU
DIE SOWO PE OHUNRE,EJIOGBE NI IFA RE.....OHUN RE....ORI NI AWONRINWON NI
TIFI PE LAIYE,OKO NI AGBE NFI ISU OGIRISAKO SI DI EEMI,KUTAKURA
KUTAKURA AIYE NI FI ILE SILO,KI GBOGBO AWON OTA MI,KIWON FIMISILE SAIYE
LO,EMI.....OMO.....NI KINREYIN AWON OTA MI.
EYONU ASIRI BIBO
----epo obo,aogun pepe,aoda sinu ape,aidan pupo aose
lelori,odidi atare kan,aojo po aomafi omi aye lo lararo pelu ofore---oni
dandan ni taidan3x bokunrin ori owo bobinrin ori owo bomode ori owo
bagba ori owo,dandan niki emi----omo---ri owo nlanla loni,ki okunrin ati
obinrin ma gbe owo nlanla wa fun emi----omo----.ti oba wuwa alete
ejiogbe si die ti afe lo,tabi ki ape ofore nikan si ki asi lo,odaju gan
OSHOLE NLA
1. Ori Inaki kan
2. Ori Ekun kan
3. Odindi Eiye Okin kan
4. Ori Ere Nla kan ati Ase re
5. Opolopo Ewe Orijin
6. Odindi Ataare 16
Ao jo gbogbo re po... Ao da opolopo ewe Orijin yen le lori ao wa jo dadaa.. Ao lo kunna.
Ao pa Adiye Akuko kan Eje re ni ao fi pa ara Igba ti ao da Ejo oogun yii si.. Eni ti o ni ogun yi ko gbudo je ninu Adiye yen...
Ao ma fi Oti Schinap lo Ogun yi ni dede ago 1:00am oru ni ojo meta meta...
Ao gbudo ba Obinrin lo po larin Ojo Meta lehin igbati aba lo ogun yen tan....
Obinrin ti o se unkan osu ko gbudo fi owo kan ose yen oo
Aworo
Egbo orogbo, eru, ako okuta, omidun ogi, ao fi iyo tele inu oru, ao ko okuta ako si, ao ko egbo orogbo le, ao da omi ogi lelori
OGUN ALEKO TO DAJU
Orogbo, obi gbanja, etu ibon, ako okuta, esuru funfun, ege ti a nfi ngun
iyan je, ogede agbagba dudu, agbado, iyere ao fi sugar die si ao gun po
ao maa fi foko tutu mu.
Awure owo/OSHOLE OWO
Ori
aja gbigbe kan. #100 tuntun ao ki si eti otun. Ao wafi #20. Ao wafi
#200 we igbo ao kisi enu ori aja na. Ao wafi ewe sawerepepe su osuka ao
gbe ori aja na si. Ao wagbe gbogbo re sinu agbada ao fi odidi atare
kan. Ao jo papo ao mafi oti schinap lo laro laro
Aworo
Ewe ogbo meta, ao gun po mo ose dudu,ao le mo ara amu omi, ao ma po mole lararo
.Awure owo gbigba
Afara oyin, ipe ire, odidi atare kan, ao jo po, ao ro sinu igo, ao ma bu sinu ipara diedie.
Eyonu aye.
Eepo obo, imi ojo, iyere, ao lopo, ao da sinu adin eyan, ao ma fi para.
Apa mowo owo.
Atare aja, korofo tadie pa ku, ao lo ti yoo kuna, ao fi sin orun owo mejeeji yika.
Ariran ounje.
Irula didi kan, ataare odidi kan, ao jo po, ao fi sin orun owo mejeeji yika
Afaro./ AWORO
owo ati ese elede mererin,ewe
ahoyoyo ao ko tele isasun,ao ko owo ati ese
elede ye si lori,ao wa ko ara eran elede ye ti koni
egungun rara si lori,ao de pa,ao lori mole ninu
shop tabi ile ise nla.odaju
ROPAROSE ( STROKE )
eku asin 11,atare
odidi 11,ori oka 6,oga gbigbe 11,ao wa gun ninu
odo ti yoo kunna,ao gbodo fi owo ko o,ao wa
gun ni agunmu,ao ma fimu eko gbigbona sibi
kookan.
OGUN TI OBINRIN KO BAA LOYUN
Eku Emo kan, Ewe Patanmo, Emo Agbo, Emo Ajao, Odindi Ataare kan ao jo
ogun yii papo, Obinrin naa yio maa fi foko tutu mun ni ojo keji ti o baa
pari nkan osu re...... Ko gbodo ri Okunrin fun ojo marun .
ATOSI
.Ao toju Bara nla kan, ao wo gbogbo omo inu re danu, ao be epo ara re
pelu ao waa ge si wewe sinu Ogidi emun tabi omi Oronbo ao daa Kaun
bilala si.. Lehin ojo keta ni ao mamu ni Gas kekere kookan lararo.
AYETA IBON
Ewe Bomubomu gbigbe 16 . Eyo Atare 16 . Ewe Owo Gbigbe 16
ao lo papo, ti o ba je wipe Awon ewe yen je tutu, ao sa si ategun a
gbudo sa si orun o, ao lo kunna daadaa, ao fi sin gbere lati isale ese
waa de arin ori.
Odaju.
Aworo.
Ifun akuko adie, ako alangba 1, ewe sawerepepe, odidi
atare kan, aa wa ko gbogbo re sinu akeregbe kekere, a awa da iyo le
lori, a wa fi aso funfun di lenu, a wa so ko si enu ona abawole.
Awure ose itaja.
Igo oyin gidi kan, lofinda bintu merin, ori osin, ori ere, ose
dudu, awa gunpo, ao ko si inu awo tanganran olomori, ao wa we laso
funfun, ao wa ma fiwe lararo.
Osole.
Ipe ire mesan, odidi ejo kan, odidi awo lili kan, padi atare kan, a jopo aa lo kuna, a ma fi foko mu lararo.
AFUNJE
Awo Ewure dudu, Ewe Amunimuye, Irun Abe, ekana owo mewewa ati ese
mewewa, irun Ipenpeju die, irun Ori die ao jo pelu Odindi ataare kan, ao
maa fun enia je.
Ise anu.
Obi ifin kan, a age si 201, obi pupa kan, a age si 201,
eyo atare 201, ao fi omi omu po papo, ao ro sinu ado ijamo kekere, ao fi
awo ijimere ran, aa wa ma fisapo.
Awure owo.
Oga aye, tagiri, igbe ewure to bimo re, igbe aguntan to bimu ri . ose dudu 300, ao gun po, ao
ma fiwe lararo:
(gbolohun re) “boro boro lewure su mi re,
boro boro laguntan su mi re, ojojumo ni tagiri nka owo tie, aba ti
alagemo bada ni orisa oke ngba, mo daba ki won ma mu nla nla wa fun mi
loni.
Awure owo.
Egbo iroko, egbo ipon, karagba idi esu, ose dudu, ao gun gbogbo re po, ao ma fi we lararo.,
gbolohun: “ipon loni kan pinre temi fun mi loni, iroko loni afaro.
ATUDE RIRISE BI WON BAA DE OWO ENIA
Ao
waa Odindi bara kan ao gesi 16 ao ko tele ape ao
wa
gbe ori Olongbo tonirun le lori ao fi odindi ataare
kan si
legbe ao jo ao popo ma ose dudu ao mafi we owo wa
mejeji pelu Gbolohun yii
Iba akoda iba aseda iba eyin aye ewa tumi nide
edi kidi bara ki gbogbo ide owo mi kotu danu ki
owo mi bere si ya fun owo nla nla ki magba ise
kekere owo nla nla, ao maa se adua to ba wuwa si
eyan pupo lelo ose
Awure.
Ori ikun kan, ori agbigbo(dododo) kan, padi ataare kan, ao jopo ao ro sinu ado ide. Lilo re> Ao bu die si owo ao pe ofo re so ao da senu ao fi hot sin Ofo re> Agbigbo oma kuu eru o (3ce), ikun(remi) loni ki efi owo owoyin kun owo towa nile(mido), ikun loni ki efikun owo mi
KOKORO OMUN OBINRIN
Ewe Egele, ireke, ogede wewe ti ko gbo, eru, epo pupa die ao fi omi
orombo si ao waa se ao maa fi we omu naa ao si maa mun ni ibe
OOGUN OUNMO TABI ARIRAN TODAJU
Ao wa Eyin ororo kan ao soro kelekele si eyin naa, iru unkan ti afe
lofun, ao wa loja ewe bomu bomu eyo mefa ao fi we eyin yi ti koni han
sita raaraa ao fi unkan di daadaa ao wa dana edu sile ao wa gbekana
bi igba ta nsun eran suya ti o baji na ao bo eyin naa ao je tabafe ki
iseyi lagbara daada ao se lemete larin osukan, opolopo kan ni a maa ri
loju aye ati orun pelu
EYONU AWON AGBA TODAJU
----eyin adie ororo 3,aofi tele ape,aoko epo obo
lelori,odidi atare kan,ewe anu,ewe orijin,ewe ajeobale,ewe owo,ewe
oyo,aojo gbogbo re po,aolo iyo mo,ogbe iyonu ni ifare--OHUN
RE---haa!3x,olukibinu olu 3x,osinkibinu osin 3x,obajalaye ki binu oba
ajalorun 3x,oba ajalorun ki binu oba ajawole 3x obajawole ki binu oba
aja dobiridobiri 3x oba aja dobiridobiri ki binu oba atiledilele 3x
otoku ilu ki binu ko iyosile komaje 3x oso ki binu kiwon ko iyo sile
kanmaje 3x enikan ki fi oyin senu kotu ito 3x beni enikan ki fi iyo senu
ko pose 3x mulobe ni oruko ti ifa npe iyo,yowon ninu gerege ki omode
mayonu simi,ki agbalagba ma yonu simi------emi-omo----lati oni lo.eyiti
abafe dasinu oyin laote ni ogbe iyonu ooo,aomala lararo
please do
MY AJEOGUN first, before doing all my medicine to make it work for u
Do it is working perfect
thehomeofsuccess@gmail.com
call or whatsapp 08027449908 or 08064941611